Num 26:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi li awọn ọmọ Dani gẹgẹ bi idile wọn: ti Ṣuhamu, idile awọn ọmọ Ṣuhamu. Wọnyi ni idile Dani gẹgẹ bi idile wọn.

Num 26

Num 26:34-52