Kol 1:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ẹniti Ọlọrun fẹ lati fi ọrọ̀ ohun ijinlẹ yi larin awọn Keferi hàn fun, ti iṣe Kristi ninu nyin, ireti ogo:

Kol 1

Kol 1:23-29