Kol 1:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani ohun ijinlẹ ti o ti farasin lati aiyeraiye ati lati irandiran, ṣugbọn ti a ti fihàn nisisiyi fun awọn enia mimọ́ rẹ̀:

Kol 1

Kol 1:24-29