Joṣ 2:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun Joṣua pe, Nitõtọ li OLUWA ti fi gbogbo ilẹ na lé wa lọwọ; nitoripe ọkàn gbogbo awọn ara ilẹ yi di omi nitori wa.

Joṣ 2

Joṣ 2:20-24