Joṣ 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li awọn ọkunrin meji na pada, nwọn si sọkalẹ lori òke, nwọn si kọja, nwọn si tọ̀ Joṣua ọmọ Nuni wá; nwọn si sọ ohun gbogbo ti o bá wọn fun u.

Joṣ 2

Joṣ 2:14-24