Joṣ 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

JOṢUA si dide ni kùtukutu owurọ̀, nwọn si ṣí kuro ni Ṣittimu, nwọn si dé Jordani, on ati gbogbo awọn ọmọ Israeli; nwọn si sùn sibẹ̀ ki nwọn ki o to gòke odò.

Joṣ 3

Joṣ 3:1-4