2. Kro 30:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti ọba ti gbìmọ ati awọn ijoye rẹ̀, ati gbogbo ijọ-enia ni Jerusalemu, lati pa ajọ irekọja mọ́ li oṣù keji.

2. Kro 30

2. Kro 30:1-8