2. Kro 30:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti nwọn kò le pa a mọ́ li akokò na, nitori awọn alufa kò ti iyà ara wọn si mimọ́ to; bẹ̃li awọn enia kò ti ikó ara wọn jọ si Jerusalemu.

2. Kro 30

2. Kro 30:1-12