Iṣe Apo 7:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kò si fun u ni ini kan, ani to bi ẹsẹ ilẹ kan; ṣugbọn o leri pe, on ó fi i fun u ni ilẹ-nini, ati fun awọn irú-ọmọ rẹ̀ lẹhin rẹ̀, nigbati kò ti ili ọmọ.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:1-9