Iṣe Apo 7:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o jade kuro ni ilẹ awọn ara Kaldea, o si ṣe atipo ni Harani: lẹhin igbati baba rẹ̀ kú, Ọlọrun mu u ṣipo pada wá si ilẹ yi, nibiti ẹnyin ngbé nisisiyi.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:1-12