Iṣe Apo 7:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si sọ bayi pe, irú-ọmọ rẹ̀ yio ṣe atipo ni ilẹ àjeji; nwọn ó si sọ wọn di ẹru, nwọn o si pọ́n wọn loju ni irinwo ọdún.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:4-12