Iṣe Apo 5:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin ọkunrin yi ni Juda ti Galili dide lakoko kikà enia, o si fà enia pipọ lẹhin rẹ̀: on pẹlu ṣegbé; ati gbogbo iye awọn ti o gbà tirẹ̀, a fọn wọn ká.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:36-42