Iṣe Apo 5:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ṣaju ọjọ wọnyi ni Teuda dide, o nwipe ẹni nla kan li on; ẹniti ìwọn irinwo ọkunrin gbatì: ẹniti a pa; ati gbogbo iye awọn ti o gbà tirẹ̀, a tú wọn ká, a si sọ wọn di asan.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:30-42