Iṣe Apo 5:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ emi wi fun nyin nisisiyi, Ẹ gafara fun awọn ọkunrin wọnyi, ki ẹ si jọwọ wọn jẹ: nitori bi ìmọ tabi iṣẹ yi ba jẹ ti enia, a o bì i ṣubu:

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:36-42