Iṣe Apo 28:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn nwoye igbati yio wú, tabi ti yio si ṣubu lulẹ kú lojiji: nigbati nwọn wò titi, ti nwọn kò si ri nkankan ki o ṣe e, nwọn pa iyè da pe, oriṣa kan li ọkunrin yi.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:2-11