Iṣe Apo 28:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li àgbegbe ibẹ̀ ni ilẹ ọkunrin ọlọlá erekuṣu na wà, orukọ ẹniti a npè ni Publiu; ẹniti o gbà wa si ọdọ, ti o si fi inu rere mu wa wọ̀ ni ijọ mẹta.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:3-8