Iṣe Apo 27:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si ké idakọró kuro, nwọn jọ̀wọ wọn sinu okun, lẹsẹkanna nwọn tu ide ọkọ̀, nwọn si ta igbokun iwaju ọkọ̀ si afẹfẹ, nwọn wa kọju si ilẹ.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:32-44