Iṣe Apo 27:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ilẹ si mọ, nwọn kò mọ̀ ilẹ na: ṣugbọn nwọn ri apa odò kan ti o li ebute, nibẹ̀ ni nwọn gbero, bi nwọn o ba le tì ọkọ̀ si.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:36-42