Iṣe Apo 27:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn jẹun yó tan, nwọn kó nkan danù kuro ninu ọkọ̀, nwọn si kó alikama dà si omi.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:30-39