Iṣe Apo 27:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si de ibiti okun meji pade, nwọn fi ori ọkọ̀ sọlẹ; iwaju rẹ̀ si kàn mọlẹ ṣinṣin, o duro, kò le yi, ṣugbọn agbara riru omi bẹrẹ si fọ́ idi ọkọ̀ na.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:36-44