Iṣe Apo 22:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi emi kò si ti le riran nitori itànṣan imọlẹ na, a ti ọwọ́ awọn ti o wà lọdọ mi fà mi, mo si de Damasku.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:4-15