Iṣe Apo 22:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si wipe, Kini ki emi ki o ṣe, Oluwa? Oluwa si wi fun mi pe, Dide, ki o si lọ si Damasku; nibẹ̀ li a o si sọ ohun gbogbo fun ọ ti a yàn fun ọ lati ṣe.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:8-13