Iṣe Apo 22:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o si wà pẹlu mi ri imọlẹ na nitõtọ, ẹ̀ru si ba wọn; ṣugbọn nwọn kò gbọ́ ohùn ẹniti mba mi sọrọ.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:1-16