Iṣe Apo 22:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikan si tọ̀ mi wá, Anania, ọkunrin olufọkansìn gẹgẹ bi ofin, ti o li orukọ rere lọdọ gbogbo awọn Ju ti o ngbe ibẹ̀.

Iṣe Apo 22

Iṣe Apo 22:6-21