Iṣe Apo 2:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si gbọ́, ọkàn wọn gbọgbẹ, nwọn si sọ fun Peteru ati awọn aposteli iyokù pe, Ará, kini ki awa ki o ṣe?

Iṣe Apo 2

Iṣe Apo 2:30-41