Iṣe Apo 2:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Peteru si wi fun wọn pe, Ẹ ronupiwada, ki a si baptisi olukuluku nyin li orukọ Jesu Kristi fun idariji ẹ̀ṣẹ nyin, ẹnyin o si gbà ẹbun Ẹmi Mimọ́.

Iṣe Apo 2

Iṣe Apo 2:34-45