Iṣe Apo 2:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ki gbogbo ile Israeli ki o mọ̀ dajudaju pe, Ọlọrun ti fi Jesu na, ti ẹnyin kàn mọ agbelebu, jẹ Oluwa ati Kristi.

Iṣe Apo 2

Iṣe Apo 2:29-46