Iṣe Apo 19:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati nwọn mọ̀ pe Ju ni, gbogbo wọn li ohùn kan, niwọn wakati meji ọjọ, kigbe pe, Oriṣa nla ni Diana ti ara Efesu.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:24-41