Iṣe Apo 19:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fà Aleksanderu kuro li awujọ, awọn Ju tì i ṣaju. Aleksanderu si juwọ́ si wọn, on iba si wi ti ẹnu rẹ̀ fun awọn enia.

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:31-36