Iṣe Apo 19:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati akọwe ilu si mu ki ijọ enia dakẹ, o ni, Ẹnyin ará Efesu, tali ẹniti o wà ti kò mọ̀ pe, ilu ara Efesu ni iṣe olusin Diana oriṣa nla, ati ti ere ti o ti ọdọ Jupiteri bọ́ silẹ?

Iṣe Apo 19

Iṣe Apo 19:27-41