Iṣe Apo 18:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si sọ fun Paulu li oru li ojuran pe, Má bẹ̀ru, sá mã sọ, má si ṣe pa ẹnu rẹ mọ́:

Iṣe Apo 18

Iṣe Apo 18:1-13