Iṣe Apo 18:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Krispu, olori sinagogu, o gbà Oluwa gbọ́ pẹlu gbogbo ile rẹ̀; ati ọ̀pọ ninu awọn ara Korinti, nigbati nwọn gbọ́, nwọn gbagbọ́, a si baptisi wọn.

Iṣe Apo 18

Iṣe Apo 18:5-16