Iṣe Apo 18:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti emi wà pẹlu rẹ, kò si si ẹniti yio dide si ọ lati pa ọ lara: nitori mo li enia pipọ ni ilu yi.

Iṣe Apo 18

Iṣe Apo 18:1-13