Iṣe Apo 17:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn Ju jowu, nwọn si fà awọn jagidijagan ninu awọn ijajẹ enia mọra, nwọn gbá ẹgbẹ jọ, nwọn si nrú ilu; nwọn si kọlù ile Jasoni, nwọn nfẹ mu wọn jade tọ̀ awọn enia wá.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:1-8