Iṣe Apo 17:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

A si yi ninu wọn lọkàn pada, nwọn si darapọ̀ mọ́ Paulu on Sila; ati ninu awọn olufọkansìn Hellene ọ̀pọ pupọ, ati ninu awọn obinrin ọlọlá, kì iṣe diẹ.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:3-13