Iṣe Apo 17:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn kò si ri wọn, nwọn wọ́ Jasoni, ati awọn arakunrin kan tọ̀ awọn olori ilu lọ, nwọn nkigbe pe, Awọn wọnyi ti o ti yi aiye po wá si ihinyi pẹlu;

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:1-10