Iṣe Apo 17:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ninu rẹ̀ li awa gbé wà li ãye, ti awa nrìn kiri, ti a si li ẹmí wa; bi awọn kan ninu awọn olorin, ẹnyin tikaranyin ti wipe, Awa pẹlu si jẹ ọmọ rẹ̀.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:18-34