Iṣe Apo 17:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o le mã wá Oluwa, boya bi ọkàn wọn ba le fà si i, ti wọn si ri i, bi o tilẹ ṣe pe kò jina si olukuluku wa:

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:17-34