Iṣe Apo 17:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ bi awa ba ṣe ọmọ Ọlọrun, kò yẹ fun wa ki a rò pe, Iwa-Ọlọrun dabi wura, tabi fadaka, tabi okuta, ti a fi ọgbọ́n ati ihumọ enia ṣe li ọnà.

Iṣe Apo 17

Iṣe Apo 17:21-34