Iṣe Apo 16:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati a si baptisi rẹ̀, ati awọn ará ile rẹ̀, o bẹ̀ wa, wipe, Bi ẹnyin ba kà mi li olõtọ si Oluwa, ẹ wá si ile mi, ki ẹ si wọ̀ nibẹ̀. O si rọ̀ wa.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:8-18