Iṣe Apo 16:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati obinrin kan ti orukọ rẹ̀ ijẹ Lidia, elesè àluko, ara ilu Tiatira, ẹniti o nsìn Ọlọrun, o gbọ́ ọ̀rọ wa: ọkàn ẹniti Oluwa ṣí, fetísi ohun ti a ti ẹnu Paulu sọ.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:13-19