Iṣe Apo 16:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọjọ isimi, awa si jade lọ si ẹhin odi ilu na, lẹba odò kan, nibiti a rò pe ibi adura wà; awa si joko, a si ba awọn obinrin ti o pejọ sọrọ.

Iṣe Apo 16

Iṣe Apo 16:11-16