Iṣe Apo 13:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Paulu si dide duro, o si juwọ́ si wọn, o ni, Ẹnyin enia Israeli, ati ẹnyin ti o bẹ̀ru Ọlọrun, ẹ fi etí silẹ.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:9-20