Iṣe Apo 13:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun awọn enia Israeli yi, yàn awọn baba wa, o si gbé awọn enia na leke, nigbati nwọn ṣe atipo ni ilẹ Egipti, apá giga li o si fi mu wọn jade kuro ninu rẹ̀.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:12-19