Iṣe Apo 13:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lẹhin kìka iwe ofin ati iwe awọn woli, awọn olori sinagogu ranṣẹ si wọn, pe, Ará, bi ẹnyin ba li ọ̀rọ iyanju kan fun awọn enia, ẹ sọ ọ.

Iṣe Apo 13

Iṣe Apo 13:9-20