Iṣe Apo 1:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

A sá kọ ọ ninu Iwe Psalmu pe, Jẹ ki ibujoko rẹ̀ ki o di ahoro, ki ẹnikan ki o má si ṣe gbé inu rẹ̀, ati oyè rẹ̀, ni ki ẹlomiran gbà.

Iṣe Apo 1

Iṣe Apo 1:18-23