Iṣe Apo 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si di mimọ̀ fun gbogbo awọn ti ngbe Jerusalemu; nitorina li a fi npè igbẹ́ na ni Akeldama li ède wọn, eyini ni, Igbẹ́ ẹ̀jẹ.

Iṣe Apo 1

Iṣe Apo 1:11-26