Hos 14:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Efraimu yio wipe, Kili emi ni fi òriṣa ṣe mọ? Emi ti gbọ́, mo si ti kiyesi i: emi dabi igi firi tutù. Lati ọdọ mi li a ti ri èso rẹ.

Hos 14

Hos 14:1-9