Hos 14:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ti o ngbe abẹ ojiji rẹ̀ yio padà wá; nwọn o sọji bi ọkà: nwọn o si tanná bi àjara: õrun rẹ̀ yio dabi ọti-waini ti Lebanoni.

Hos 14

Hos 14:5-9