Gẹn 18:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Jọ̃, ki inu ki o máṣe bi OLUWA, ẹ̃kanṣoṣo yi li emi o si wi mọ. Bọya a o ri mẹwa nibẹ̀. On si wipe, Emi ki yio run u nitori mẹwa.

Gẹn 18

Gẹn 18:31-33